Ayeofe Lyrics – Root Music | Barry Jhay x Vstix

Ayeofe Lyrics – Root Music | Barry Jhay x Vstix lyrics

Poster  Ayeofe Lyrics – Root Music | Barry Jhay x Vstix

Ayeofe Lyrics – Root Music | Barry Jhay x Vstix

Details
Language Afrobeats
Poster  Ayeofe Lyrics – Root Music | Barry Jhay x Vstix
play
Lyrics

O le le, o, o omo
Call me Barry
Oya see
Ati wa aye ko ni a ri

Eni ori yo o di ile
Ile koko ni ti agbe
Ile labo simi oko
Kekere la ta tin so pe fun oju

Eni awi fun oba je ogbo
Eni a soro fun ona je o gba
Ma je ki oya a le ti la pa
Eso pe le la aye gba

Ore mi je ki a se jeje
Ara la mo a mo inu
Oju la ri
A i mo inu eni kan

Ti won ba n to n e
Ore ma tan ara e
Ti ori ba n yo e
Ore yo ara e

Ko si eni fe ni fun ire
A fi ori eni
Ayeofe o jare
Eni o fe ooo
Eni yan o da

Eniyan o fe ka gbe eru do ori
Ori eni sha lo n ba ni gbe o
Eniyan o fe ka re ru kaso
Ore e ni

Ore e ni

Eniyan o fe ka re ru kaso
Ori eni sha
Ori eni sha lo yo ni

Ile aye ta wa awa na ja ni
Bo pe bo ya
Ka lu ku a pa da si ile o

Orun sha ni ile
Orun sha ni ile gbogbo wa

Bo pe boya a ki lo lo a pe baba
Bo pe boya agan a pada di olomo
Olorun o le fi wa si le fun iya je
Ojojumo yo gbe leyin omo e

Ayeofe o jare
Eni o fe ooo
Eni yan o da

Eniyan o fe ka gbe eru do ori
Ori eni sha lo n ba ni gbe o

Eniyan o fe ka re ru kaso
Ore e ni
Ore e ni

Eniyan o fe ka re ru kaso
Ori eni sha
Ori eni sha lo yo ni

Eni ori yo o di ile
Ile koko ni ti agbe
Ile labo simi oko
Kekere la ta tin so pe fun oju

Eni awi fun oba je ogbo
Eni a soro fun ona je o gba
Ma je ki oya a le ti la pa

You May Also Like (Similar)

Advertisement
Note: Discover a wide collection of free lyrics on this website. Please note that we ("asomlive") do not host the files.
Rules: Videos and lyrics provided are for personal use only. Redistribution of these materials is strictly prohibited. Please delete them from your hard disk within 24 hours. If you do not agree with these terms, please close this window.